
Balogun-Boje Habeebah
Podcast de Balogun-Boje Habeebah
My podcast is all about Culture
Disfruta 90 días gratis
9,99 € / mes después de la prueba.Cancela cuando quieras.
Todos los episodios
3 episodios
Órìkì je Òkan làrá àwón àsá yórúbà tí a má gbá latí fí kì eníhàn tábí gbé órìyín fún énìyán nì ílé yórúbà.

Ẹkún Ìyàwó jẹ́ ewì-àbáláyé nílẹ̀ Yorùbá. Ó jẹ́ ẹkún tí omidan tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ lọlé ọkọ máa ń sún láti dárò bí ó ṣe fẹ́ filé àwọn òbí rẹ̀ sílẹ̀ lọlé ọkọ àti láti súre fún wọn fún titọ́ ọ dàgbà di àkókò náà. Ẹkún Ìyàwó jẹ́ pàtàkì àṣeyẹ nínú àṣà ìgbéyàwó láwùjọ ọmọ Oòduà.

Ìgbéyàwó jẹ́ ìdarapọ̀ṣọ̀kan ọlọ́mọge tó ti bàlágà, tàbí obìnrin adélébọ̀ àti àpọ́n tàbí ọkùnrin géńdé tó tójú bó láti di ọkọ àti aya.
Disfruta 90 días gratis
9,99 € / mes después de la prueba.Cancela cuando quieras.
Podcasts exclusivos
Sin anuncios
Podcast gratuitos
Audiolibros
100 horas / mes